So So ... Kingg Oogbodo Inu N Bi Mi lyrics, videos

Lyrics, artwork, videos of the trending Kingg Oogbodo evergreen afrobeats smash hit Inu N Bi Mi

Intro

So So

Blood Entertainment

Eje

Kingg Oogbodo

Shocker production

This one

Is Inu N Bi Mi

Cos I’m very angry

At the way things are in Nigeria


Chorus (2x)

Inu n bi mi (2x)

Inu n bi mi ye

Me I dey vex

I dey para

Still me dey hala say say say

Verse 1

Inu n bi mi

Si Nigeria

Bo se ri

Awa to je pe

Awa ni giant Africa

Nisinyi

Ati di laughing stock

Of same Africa
Ko si ti ti

Ko s’omi

Ko s’ina

Ko s’owo lapo awon ara’lu

Ki lo de fa

Awon olori wa ni

Won dari wa dada

T’awon boys ba de k’orin

Pe Nigeria o da

Pe Nigeria jaga jaga

Awon olori wa a tu n ma binu

Won a so pe

Awon boys o wa

Patriotic

Whereas

To ri pe awa

Patriotic

La fi n f’ohun le

Bi Baba Fela

K’atunse ba le wa

Iwa pala pala awon olori wa yi

Lo n je k’inu ma bi mi gan

Repeat chorus (2x)

See also

Verse 2

Ti n ba kan ti e ro n gba mi

Ori ma n fo mi ni

S’ese ni pe k’eyan j’omo Nigeria ni

Ki la gbe, ki la ju

Oju apa o ma le da b’oju ara

Gbogbo’ya t’ati je yi

A le gba gbe e

Tor’iya ki n s’omi obe

Awa to ye ka da ju China at’America

Sugbon b’oya gan la da to Ghana

What a shame

And an embarrassment
Kingg Oogbodo Inu N Bi Mi artwork
E ja p’obo l’obo

Adiye l’adiye

Nigeria o da

Awon olori wa lo de fa

E wa so pe k’inu ma bi mi

Inu n bi mi

O de n bi mi gan ni

Gan ni

Repeat chorus (2x)

Verse 3

Inu n bi mi

S’awon obi mi

Kilode te bi mi si Nigeria

Inu n bi mi

S’awon ore mi

Tan da’le mi n’gbati mo ni problem Charly Boy
Inu n bi mi

S’awon on’ise owo kan kan

E n s’ise buruku, e de n gb’owo nla

Inu n bi mi

S’awon oni’motor

E n fi’kun owo motor anyhow

Inu n bi mi

S’awon teacher

E ko awon omo school da da

Inu n bi mi

S’awon oloja kan kan

E n ta’ja ti o da

Inu n bi mi

S’awon doctor

E wo awon alaisan da da

Inu n bi mi

S’awon oyinbo to wa ni Nigeria

E n re wa je n’ilu wa

O ye ka deport gbogbo yin ni

Inu n bi mi

S’awon oga mi

Kilode te ma fun mi ten million naira lo’sosu

Inu n bi mi

S’awon osise ijoba

E n gb’egunje ke to s’ise

Inu n bi mi

S’awon NYSC

E n post awon omolomo lo si’bi ti won ti p’awon

Inu n bi mi

S’awon to n ju ado oloro

E n kan p’awon eyan bo se wu yin

Sugbon mo mo pe Olohun ma da seria fun gbogbo yin

Ahhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhh

Repeat chorus (2x)

Outro

So there you have it

We’ve got to make things work in Nigeria

Kingg Oogbodo say so

I’m very angry

Very very angry

And until Nigeria becomes the best country in the world

I’m gonna remain angry

Blood Entertainment

Eje

Comments

Popular posts from this blog

The Newell Murder serialization 1