Kingg Oogbodo Ijekuje lyrics, audio video

Lyrics (below), cover artwork (above) and audio video (below) of afrobeats smash hit Ijekuje by Kingg Oogbodo

Intro

So So (4x)

Chorus 1

O r’omo to pupa

O fe je’nbe

Ki lo fe je

Ijekuje

O r’eto dudu

O fe kakadu

Ki lo fe je

Ijekuje

Eto lepa

O fe register

Ki lo fe je

Ijekuje

Eto sanra na

O fe la mo

Ki lo fe je

Ijekuje eh (5x)

Ifakufa (4x)

Olojukokoro (3x)

Ojukokoro

Olojukokoro (3x)

Ojukokoro

Verse

Olojukokoro

Alaseju

Alasete te te

Olojukokoro

Alaseju

Alasete

L’oto ejo dun

O dun gan

At same time

Gbogbo ejo

Ko ni

Jije

Sugbon

L’odo ti’e

Gbogbo ejo

Ni jije

Kikiru

Giga

Sisanra

Lepa

Akata

Mulatto

Oyinbo

Chinko

Dulawo

O fe egbon

Ati aburo

O fe iya

Pelu omo

Ore ati ore

O p’awon

Je (6x)

La (4x)

Mi o le s’ope ko ma se nkan to fe se oh

Nkankan ni mo ko le so oh

Gbogbo nkan lo l’eyin oh (3x)

Gbogbo nkan lo l’eyin se

Chorus 2

O r’omo to pupa

O fe je’nbe

Ki lo fe je

Ijekuje

O r’eto dudu

O fe kakadu

Ki lo fe je

Ijekuje

Eto lepa

O fe register

Ki lo fe je

Ijekuje

Eto sanra na

O fe la mo

Ki lo fe je

Ijekuje eh (5x)

Ifakufa (4x)

Olojukokoro (3x)

Ojukokoro

Olojukokoro

Alaseju oh

Olojukokoro

Alasete oh

Outro

So So

It’s ur boi

Kingg Oogbodo

Representing

Blood Entertainment

Eje

Shocker on this dope beat

Beatbox mix

 

Comments

Popular posts from this blog

The Newell Murder serialization 1