Kingg Oogbodo Ife Ikeja lyrics, videos

Lyrics, artwork, audio and a cappella videos of the evergreen Kingg Oogbodo trending afrobeats smash hit Ife Ikeja

Intro (Kingg Oogbodo)

Yeah

Oseyiza King Oogbodo

Ikeja be the best, you know

Blood Entertainment

Brother

Don Drim production

That’s right

Ikeja luv, you know

Ife Ikeja, you know

Uhn

Ikeja luv

Verse 1 (Kingg Oogbodo)

Ta lo to be lati so pe oun mo Ikeja to wa ni Eko

Eko ti awon oloyinbo n pe ni Lagos State, Nigeria

Ikeja yen men

Ko s’oun ti o si n’ibe

To be je hustler

To ba hustle n’Ikeja

Gbogbo dreams e lo ma di reality

Gba bi mo se so fun e

Emi ti hustle n’Ikeja so e ma je ko ya yin l’enu pe mo n p’ariwo Ikeja

T’omode ba da

E je ka fiyin fun

Ibi pelebe l’emi ti n b’ole

O ja si pe

Mi o ki n paro

Oto ni mo de n so fun yin

Pe ninu gbogbo ilu to wa l’Eko

Ikeja, Surulere, Apapa ati bebelo

Ikeja o yato jo

Chorus (Don Drim)

Ikeja baba ni se

IKJ baba ni se

Ikeja baba ni se

IKJ baba ni se

Ikeja mo n’ife e

IKJ I luv ya

Ikeja mo n’ife e

IKJ I luv ya

Verse 2 (Kingg Oogbodo)

Nigbati mo ma koko de Ikeja

Inu mi dun bi talaka to se je one million dollars

Mo fo s’oke

Mo de pariwo ayo

Tori mo ti n ma n gbonpa Ikeja tipe tipe

Allen Avenue, Opebi, Awolowo Way ati bebelo

Aye wa n’Ikeja

Aye toju aye lo

Ti n ba paro

Ema bo mi l’asiri

Hotel to da ju ni Naija

Ikeja lo wa

Airport to da ju nko

Ikeja lo wa

Ijoba Eko na nko

Ikeja lo wa

Ijoba Eko lo de n control gbogbo nkan to n sele l’Eko

Eyin ti Lekki

Eyin ti Mushin

Bo de j’eyin ti Yaba

Gbogbo nkan te ba fe se

Repeat chorus (Don Drim)

Verse 3 (Kingg Oogbodo)

So ko need ka ma pariwo enu ju

Tori gbogbo wa la mo pe

Ika o dogba

Isu ati iyan o de ki n s’egbe

In the same vein

Ikeja o ki n s’egebe eyin ilu yoku te wa l’Eko

Eleyi o ki n s’oro ka ma taka

Ko de ki n se ijakadi

Mathematics ni

1 plus 1 is equal to 2

Repeat chorus (3x) (Don Drim)

Outro (Don Drim)

Heh heh (2x)

Oh oh

Heh heh heh yeah

Na so (2x)

Well well well well yeah

Kingg Oogbodo Ife Ikeja artwork


Comments

Popular posts from this blog

The Newell Murder serialization 1